Baba wa ti mbẹ ni ọrun,
ki a bọwọ fun orukọ rẹ.
Ki ijọba rẹ de.
Ifẹ tirẹ ni ki a ṣe,
bi ti ọrun, bẹ̃ gẹgẹ ni aiye.
Fun wa li onjẹ ojọ wa loni.
Dari gbese wa ji wa,
bi awa ti ndariji awọn onigbese wa.
Mase fa wa sinu idanwo,
ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi.
Nitori tirẹ ni ijọba, ati agbara, ati ogo, lailai.
Amin.
0
/ 40
Tap or swipe after completing the prayer